Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 29 - النَّمل - Page - Juz 19
﴿قَالَتۡ يَٰٓأَيُّهَا ٱلۡمَلَؤُاْ إِنِّيٓ أُلۡقِيَ إِلَيَّ كِتَٰبٞ كَرِيمٌ ﴾
[النَّمل: 29]
﴿قالت ياأيها الملأ إني ألقي إلي كتاب كريم﴾ [النَّمل: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Bilƙīs) sọ pé: “Ẹ̀yin ìjòyè, dájúdájú wọ́n ti ju ìwé alápọ̀n-ọ́nlé kan sí mi |