Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘Ankabut ayat 15 - العَنكبُوت - Page - Juz 20
﴿فَأَنجَيۡنَٰهُ وَأَصۡحَٰبَ ٱلسَّفِينَةِ وَجَعَلۡنَٰهَآ ءَايَةٗ لِّلۡعَٰلَمِينَ ﴾
[العَنكبُوت: 15]
﴿فأنجيناه وأصحاب السفينة وجعلناها آية للعالمين﴾ [العَنكبُوت: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A sì la òun àti àwọn èrò inú ọkọ̀ ojú-omi. A sì ṣe wọ́n ní àmì fún gbogbo ẹ̀dá |