Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘Ankabut ayat 22 - العَنكبُوت - Page - Juz 20
﴿وَمَآ أَنتُم بِمُعۡجِزِينَ فِي ٱلۡأَرۡضِ وَلَا فِي ٱلسَّمَآءِۖ وَمَا لَكُم مِّن دُونِ ٱللَّهِ مِن وَلِيّٖ وَلَا نَصِيرٖ ﴾
[العَنكبُوت: 22]
﴿وما أنتم بمعجزين في الأرض ولا في السماء وما لكم من دون﴾ [العَنكبُوت: 22]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé ẹ̀yin kò níí mórí bọ́ mọ́ Allāhu lọ́wọ́ lórí ilẹ̀ àti nínú sánmọ̀. Kò sì sí aláàbò àti alárànṣe kan fun yín lẹ́yìn Allāhu |