Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘Ankabut ayat 48 - العَنكبُوت - Page - Juz 21
﴿وَمَا كُنتَ تَتۡلُواْ مِن قَبۡلِهِۦ مِن كِتَٰبٖ وَلَا تَخُطُّهُۥ بِيَمِينِكَۖ إِذٗا لَّٱرۡتَابَ ٱلۡمُبۡطِلُونَ ﴾
[العَنكبُوت: 48]
﴿وما كنت تتلو من قبله من كتاب ولا تخطه بيمينك إذا لارتاب﴾ [العَنكبُوت: 48]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìwọ kò ké tírà kan rí ṣíwájú al-Ƙur’ān, ìwọ kò sì fi ọwọ́ ọ̀tún rẹ kọ n̄ǹkan rí. Bí bẹ́ẹ̀ kọ́ nígbà náà, kí àwọn òpùrọ́ ṣeyèméjì (sí al-Ƙur’ān) |