Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 163 - آل عِمران - Page - Juz 4
﴿هُمۡ دَرَجَٰتٌ عِندَ ٱللَّهِۗ وَٱللَّهُ بَصِيرُۢ بِمَا يَعۡمَلُونَ ﴾
[آل عِمران: 163]
﴿هم درجات عند الله والله بصير بما يعملون﴾ [آل عِمران: 163]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Èkínní kejì èrò inú Ọgbà Ìdẹ̀ra àti èrò inú Iná ni) wọ́n ní ipò (ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀) ní ọ̀dọ̀ Allāhu. Allāhu sì ni Olùríran nípa ohun tí wọ́n ń ṣe níṣẹ́ |