Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 197 - آل عِمران - Page - Juz 4
﴿مَتَٰعٞ قَلِيلٞ ثُمَّ مَأۡوَىٰهُمۡ جَهَنَّمُۖ وَبِئۡسَ ٱلۡمِهَادُ ﴾
[آل عِمران: 197]
﴿متاع قليل ثم مأواهم جهنم وبئس المهاد﴾ [آل عِمران: 197]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìgbádùn díẹ̀ (lè wà fún wọn), lẹ́yìn náà iná Jahanamọ ni ibùgbé wọn. Ibùgbé náà sì burú |