Quran with Yoruba translation - Surah Ar-Rum ayat 17 - الرُّوم - Page - Juz 21
﴿فَسُبۡحَٰنَ ٱللَّهِ حِينَ تُمۡسُونَ وَحِينَ تُصۡبِحُونَ ﴾
[الرُّوم: 17]
﴿فسبحان الله حين تمسون وحين تصبحون﴾ [الرُّوم: 17]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ẹ ṣe àfọ̀mọ́ fún Allāhu nígbà tí ẹ bá wà ní alẹ́ àti nígbà tí ẹ bá wà ní òwúrọ̀ |