Quran with Yoruba translation - Surah Luqman ayat 24 - لُقمَان - Page - Juz 21
﴿نُمَتِّعُهُمۡ قَلِيلٗا ثُمَّ نَضۡطَرُّهُمۡ إِلَىٰ عَذَابٍ غَلِيظٖ ﴾
[لُقمَان: 24]
﴿نمتعهم قليلا ثم نضطرهم إلى عذاب غليظ﴾ [لُقمَان: 24]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A máa fún wọn ní ìgbádùn díẹ̀. Lẹ́yìn náà, A máa taari wọn sínú ìyà t’ó nípọn |