Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 62 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿وَلَقَدۡ أَضَلَّ مِنكُمۡ جِبِلّٗا كَثِيرًاۖ أَفَلَمۡ تَكُونُواْ تَعۡقِلُونَ ﴾
[يسٓ: 62]
﴿ولقد أضل منكم جبلا كثيرا أفلم تكونوا تعقلون﴾ [يسٓ: 62]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé (Èṣù) kúkú ti ṣi ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ẹ̀dá lọ́nà nínú yín. Ṣé ẹ ò níí ṣe làákàyè ni |