Quran with Yoruba translation - Surah Ya-Sin ayat 82 - يسٓ - Page - Juz 23
﴿إِنَّمَآ أَمۡرُهُۥٓ إِذَآ أَرَادَ شَيۡـًٔا أَن يَقُولَ لَهُۥ كُن فَيَكُونُ ﴾
[يسٓ: 82]
﴿إنما أمره إذا أراد شيئا أن يقول له كن فيكون﴾ [يسٓ: 82]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àṣẹ Rẹ̀ nígbà tí Ó bá gbèrò kiní kan ni pé, Ó máa sọ fún un pé "Jẹ́ bẹ́ẹ̀." Ó sì máa jẹ́ bẹ́ẹ̀ |