Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 10 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿إِلَّا مَنۡ خَطِفَ ٱلۡخَطۡفَةَ فَأَتۡبَعَهُۥ شِهَابٞ ثَاقِبٞ ﴾
[الصَّافَات: 10]
﴿إلا من خطف الخطفة فأتبعه شهاب ثاقب﴾ [الصَّافَات: 10]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Wọn kò níí gbọ́ ọ̀rọ̀ ní kíkún) àyàfi ẹni tí ó bá rí ọ̀rọ̀ àjígbọ́ gbé, nígbà náà (ni mọlāika) yó sì fi ẹ̀ta ìràwọ̀ iná t’ó máa jó o tẹ̀lé e |