Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 101 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿فَبَشَّرۡنَٰهُ بِغُلَٰمٍ حَلِيمٖ ﴾
[الصَّافَات: 101]
﴿فبشرناه بغلام حليم﴾ [الصَّافَات: 101]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A sì fún un ní ìró ìdùnnú (nípa bíbí) ọmọkùnrin aláfaradà |