Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 31 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿فَحَقَّ عَلَيۡنَا قَوۡلُ رَبِّنَآۖ إِنَّا لَذَآئِقُونَ ﴾
[الصَّافَات: 31]
﴿فحق علينا قول ربنا إنا لذائقون﴾ [الصَّافَات: 31]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ọ̀rọ̀ Olúwa wa sì kò lé wa lórí pé dájúdájú àwa yóò tọ́ Iná wò |