Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 30 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿وَمَا كَانَ لَنَا عَلَيۡكُم مِّن سُلۡطَٰنِۭۖ بَلۡ كُنتُمۡ قَوۡمٗا طَٰغِينَ ﴾
[الصَّافَات: 30]
﴿وما كان لنا عليكم من سلطان بل كنتم قوما طاغين﴾ [الصَّافَات: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé àwa kò ní agbára kan lórí yín, ṣùgbọ́n ẹ̀yin jẹ́ ìjọ olùtayọ-ẹnu àlà |