Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 57 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿وَلَوۡلَا نِعۡمَةُ رَبِّي لَكُنتُ مِنَ ٱلۡمُحۡضَرِينَ ﴾
[الصَّافَات: 57]
﴿ولولا نعمة ربي لكنت من المحضرين﴾ [الصَّافَات: 57]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé tí kì í bá ṣe ìdẹ̀ra Olúwa mi ni, èmi náà ìbá wà nínú ẹni tí wọ́n máa mú wá sínú Iná |