Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 95 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿قَالَ أَتَعۡبُدُونَ مَا تَنۡحِتُونَ ﴾
[الصَّافَات: 95]
﴿قال أتعبدون ما تنحتون﴾ [الصَّافَات: 95]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ó sọ pé: "Ṣé ẹ óò máa jọ́sìn fún n̄ǹkan tí ẹ gbẹ́ kalẹ̀ lére ni |