Quran with Yoruba translation - Surah As-saffat ayat 97 - الصَّافَات - Page - Juz 23
﴿قَالُواْ ٱبۡنُواْ لَهُۥ بُنۡيَٰنٗا فَأَلۡقُوهُ فِي ٱلۡجَحِيمِ ﴾
[الصَّافَات: 97]
﴿قالوا ابنوا له بنيانا فألقوه في الجحيم﴾ [الصَّافَات: 97]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n wí pé: "Ẹ mọ ilé kan fún un, kí ẹ sì jù ú sínú iná |