Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 69 - صٓ - Page - Juz 23
﴿مَا كَانَ لِيَ مِنۡ عِلۡمِۭ بِٱلۡمَلَإِ ٱلۡأَعۡلَىٰٓ إِذۡ يَخۡتَصِمُونَ ﴾
[صٓ: 69]
﴿ما كان لي من علم بالملإ الأعلى إذ يختصمون﴾ [صٓ: 69]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Èmi kò sì nímọ̀ nípa àwọn mọlāika tí ó wà ní àyè gíga nígbà tí wọ́n ń ṣàròyé |