Quran with Yoruba translation - Surah sad ayat 85 - صٓ - Page - Juz 23
﴿لَأَمۡلَأَنَّ جَهَنَّمَ مِنكَ وَمِمَّن تَبِعَكَ مِنۡهُمۡ أَجۡمَعِينَ ﴾
[صٓ: 85]
﴿لأملأن جهنم منك وممن تبعك منهم أجمعين﴾ [صٓ: 85]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni dájúdájú Mo máa fi ìwọ àti gbogbo àwọn t’ó bá tẹ̀lé ọ nínú wọn kún inú iná Jahanamọ |