Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 38 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿وَقَالَ ٱلَّذِيٓ ءَامَنَ يَٰقَوۡمِ ٱتَّبِعُونِ أَهۡدِكُمۡ سَبِيلَ ٱلرَّشَادِ ﴾
[غَافِر: 38]
﴿وقال الذي آمن ياقوم اتبعون أهدكم سبيل الرشاد﴾ [غَافِر: 38]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹni t’ó gbàgbọ́ ní òdodo tún sọ pé: "Ẹ̀yin ènìyàn mi, ẹ tẹ̀lé mi, mo máa júwe yín sí ojú ọ̀nà ìmọ̀nà |