Quran with Yoruba translation - Surah Ghafir ayat 39 - غَافِر - Page - Juz 24
﴿يَٰقَوۡمِ إِنَّمَا هَٰذِهِ ٱلۡحَيَوٰةُ ٱلدُّنۡيَا مَتَٰعٞ وَإِنَّ ٱلۡأٓخِرَةَ هِيَ دَارُ ٱلۡقَرَارِ ﴾
[غَافِر: 39]
﴿ياقوم إنما هذه الحياة الدنيا متاع وإن الآخرة هي دار القرار﴾ [غَافِر: 39]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀yin ènìyàn mi, ìṣẹ̀mí ilé ayé yìí jẹ́ ìgbádùn lásán. Dájúdájú ọ̀run sì ni ilé gbére |