Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shura ayat 53 - الشُّوري - Page - Juz 25
﴿صِرَٰطِ ٱللَّهِ ٱلَّذِي لَهُۥ مَا فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَمَا فِي ٱلۡأَرۡضِۗ أَلَآ إِلَى ٱللَّهِ تَصِيرُ ٱلۡأُمُورُ ﴾
[الشُّوري: 53]
﴿صراط الله الذي له ما في السموات وما في الأرض ألا إلى﴾ [الشُّوري: 53]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ọ̀nà Allāhu, Ẹni tí ohunkóhun t’ó wà nínú àwọn sánmọ̀ àti ohunkóhun t’ó wà nínú ilẹ̀ ń jẹ́ tiRẹ̀. Gbọ́! Ọ̀dọ̀ Allāhu ni àwọn ọ̀rọ̀ ẹ̀dá yóò padà sí |