Quran with Yoruba translation - Surah Az-Zukhruf ayat 72 - الزُّخرُف - Page - Juz 25
﴿وَتِلۡكَ ٱلۡجَنَّةُ ٱلَّتِيٓ أُورِثۡتُمُوهَا بِمَا كُنتُمۡ تَعۡمَلُونَ ﴾
[الزُّخرُف: 72]
﴿وتلك الجنة التي أورثتموها بما كنتم تعملون﴾ [الزُّخرُف: 72]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyẹn ni Ọgbà Ìdẹ̀ra tí A jogún rẹ̀ fun yín nítorí ohun tí ẹ̀ ń ṣe níṣẹ́ |