Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 12 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿رَّبَّنَا ٱكۡشِفۡ عَنَّا ٱلۡعَذَابَ إِنَّا مُؤۡمِنُونَ ﴾
[الدُّخان: 12]
﴿ربنا اكشف عنا العذاب إنا مؤمنون﴾ [الدُّخان: 12]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Àwọn ènìyàn yóò wí pé): Olúwa wa, gbé ìyà náà kúrò fún wa, dájúdájú àwa yóò gbàgbọ́ ní òdodo |