Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 13 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿أَنَّىٰ لَهُمُ ٱلذِّكۡرَىٰ وَقَدۡ جَآءَهُمۡ رَسُولٞ مُّبِينٞ ﴾
[الدُّخان: 13]
﴿أنى لهم الذكرى وقد جاءهم رسول مبين﴾ [الدُّخان: 13]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Báwo ni ìrántí ṣe lè wúlò fún wọn (lásìkò ìyà)? Òjíṣẹ́ pọ́nńbélé kúkú ti dé bá wọn |