Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 14 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿ثُمَّ تَوَلَّوۡاْ عَنۡهُ وَقَالُواْ مُعَلَّمٞ مَّجۡنُونٌ ﴾ 
[الدُّخان: 14]
﴿ثم تولوا عنه وقالوا معلم مجنون﴾ [الدُّخان: 14]
| Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, wọ́n gbúnrí kúrò ní ọ̀dọ̀ rẹ̀. Wọ́n sì wí pé: "Wèrè tí ènìyàn kan ń kọ́ ní ẹ̀kọ́ ni  |