Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 3 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿إِنَّآ أَنزَلۡنَٰهُ فِي لَيۡلَةٖ مُّبَٰرَكَةٍۚ إِنَّا كُنَّا مُنذِرِينَ ﴾
[الدُّخان: 3]
﴿إنا أنـزلناه في ليلة مباركة إنا كنا منذرين﴾ [الدُّخان: 3]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Àwa sọ̀ ọ́ kalẹ̀ nínú òru ìbùkún. Dájúdájú Àwa ń jẹ́ Olùkìlọ̀ |