Quran with Yoruba translation - Surah Ad-Dukhan ayat 41 - الدُّخان - Page - Juz 25
﴿يَوۡمَ لَا يُغۡنِي مَوۡلًى عَن مَّوۡلٗى شَيۡـٔٗا وَلَا هُمۡ يُنصَرُونَ ﴾
[الدُّخان: 41]
﴿يوم لا يغني مولى عن مولى شيئا ولا هم ينصرون﴾ [الدُّخان: 41]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ní ọjọ́ tí ọ̀rẹ́ kan kò níí fi kiní kan rọ ọ̀rẹ́ kan lọ́rọ̀. A ò sì níí ràn wọ́n lọ́wọ́ |