Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ahqaf ayat 14 - الأحقَاف - Page - Juz 26
﴿أُوْلَٰٓئِكَ أَصۡحَٰبُ ٱلۡجَنَّةِ خَٰلِدِينَ فِيهَا جَزَآءَۢ بِمَا كَانُواْ يَعۡمَلُونَ ﴾
[الأحقَاف: 14]
﴿أولئك أصحاب الجنة خالدين فيها جزاء بما كانوا يعملون﴾ [الأحقَاف: 14]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn wọ̀nyẹn ni èrò inú Ọgbà Ìdẹ̀ra. Olùṣegbére ni wọ́n nínú rẹ̀. (Ó jẹ́) ẹ̀san nítorí ohun tí wọ́n ń ṣe níṣẹ́ |