×

Seranti arakunrin (ijo) ‘Ad. Nigba ti o sekilo fun awon eniyan re 46:21 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Ahqaf ⮕ (46:21) ayat 21 in Yoruba

46:21 Surah Al-Ahqaf ayat 21 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ahqaf ayat 21 - الأحقَاف - Page - Juz 26

﴿۞ وَٱذۡكُرۡ أَخَا عَادٍ إِذۡ أَنذَرَ قَوۡمَهُۥ بِٱلۡأَحۡقَافِ وَقَدۡ خَلَتِ ٱلنُّذُرُ مِنۢ بَيۡنِ يَدَيۡهِ وَمِنۡ خَلۡفِهِۦٓ أَلَّا تَعۡبُدُوٓاْ إِلَّا ٱللَّهَ إِنِّيٓ أَخَافُ عَلَيۡكُمۡ عَذَابَ يَوۡمٍ عَظِيمٖ ﴾
[الأحقَاف: 21]

Seranti arakunrin (ijo) ‘Ad. Nigba ti o sekilo fun awon eniyan re t’o n gbe ninu yanrin ti ategun kojo bi oke. Awon olukilo si ti re koja siwaju re ati leyin re. (O si so pe:) "Eyin ko gbodo josin fun kini kan ayafi Allahu. Dajudaju emi n paya iya ojo nla kan fun yin

❮ Previous Next ❯

ترجمة: واذكر أخا عاد إذ أنذر قومه بالأحقاف وقد خلت النذر من بين, باللغة اليوربا

﴿واذكر أخا عاد إذ أنذر قومه بالأحقاف وقد خلت النذر من بين﴾ [الأحقَاف: 21]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Ṣèrántí arákùnrin (ìjọ) ‘Ād. Nígbà tí ó ṣèkìlọ̀ fún àwọn ènìyàn rẹ̀ t’ó ń gbé nínú yanrìn tí atẹ́gùn kójọ bí òkè. Àwọn olùkìlọ̀ sì ti ré kọjá ṣíwájú rẹ̀ àti lẹ́yìn rẹ̀. (Ó sì sọ pé:) "Ẹ̀yin kò gbọdọ̀ jọ́sìn fún kiní kan àyàfi Allāhu. Dájúdájú èmi ń páyà ìyà ọjọ́ ńlá kan fun yín
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek