×

Nigba ti won ri iya naa ni esujo regede, t’o n wo 46:24 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Ahqaf ⮕ (46:24) ayat 24 in Yoruba

46:24 Surah Al-Ahqaf ayat 24 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Ahqaf ayat 24 - الأحقَاف - Page - Juz 26

﴿فَلَمَّا رَأَوۡهُ عَارِضٗا مُّسۡتَقۡبِلَ أَوۡدِيَتِهِمۡ قَالُواْ هَٰذَا عَارِضٞ مُّمۡطِرُنَاۚ بَلۡ هُوَ مَا ٱسۡتَعۡجَلۡتُم بِهِۦۖ رِيحٞ فِيهَا عَذَابٌ أَلِيمٞ ﴾
[الأحقَاف: 24]

Nigba ti won ri iya naa ni esujo regede, t’o n wo bo wa sinu awon koto ilu won, won wi pe: "Eyi ni esujo regede, ti o maa rojo fun wa." Ko si ri bee, ohun ti e n wa pelu ikanju ni. Ategun ti iya eleta-elero wa ninu re ni

❮ Previous Next ❯

ترجمة: فلما رأوه عارضا مستقبل أوديتهم قالوا هذا عارض ممطرنا بل هو ما, باللغة اليوربا

﴿فلما رأوه عارضا مستقبل أوديتهم قالوا هذا عارض ممطرنا بل هو ما﴾ [الأحقَاف: 24]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Nígbà tí wọ́n rí ìyà náà ní ẹ̀ṣújò rẹgẹdẹ, t’ó ń wọ́ bọ̀ wá sínú àwọn kòtò ìlú wọn, wọ́n wí pé: "Èyí ni ẹ̀ṣújò rẹgẹdẹ, tí ó máa rọ̀jò fún wa." Kò sì rí bẹ́ẹ̀, ohun tí ẹ̀ ń wá pẹ̀lú ìkánjú ni. Atẹ́gùn tí ìyà ẹlẹ́ta-eléro wà nínú rẹ̀ ni
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek