Quran with Yoruba translation - Surah Muhammad ayat 11 - مُحمد - Page - Juz 26
﴿ذَٰلِكَ بِأَنَّ ٱللَّهَ مَوۡلَى ٱلَّذِينَ ءَامَنُواْ وَأَنَّ ٱلۡكَٰفِرِينَ لَا مَوۡلَىٰ لَهُمۡ ﴾
[مُحمد: 11]
﴿ذلك بأن الله مولى الذين آمنوا وأن الكافرين لا مولى لهم﴾ [مُحمد: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ìyẹn nítorí pé dájúdájú Allāhu ni Olùrànlọ́wọ́ àwọn t’ó gbàgbọ́ ní òdodo. Dájúdájú àwọn aláìgbàgbọ́, kò sí olùrànlọ́wọ́ kan fún wọn |