Quran with Yoruba translation - Surah Muhammad ayat 27 - مُحمد - Page - Juz 26
﴿فَكَيۡفَ إِذَا تَوَفَّتۡهُمُ ٱلۡمَلَٰٓئِكَةُ يَضۡرِبُونَ وُجُوهَهُمۡ وَأَدۡبَٰرَهُمۡ ﴾
[مُحمد: 27]
﴿فكيف إذا توفتهم الملائكة يضربون وجوههم وأدبارهم﴾ [مُحمد: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Báwo ni (ó ṣe máa rí) nígbà tí àwọn mọlāika bá gba ẹ̀mí wọn, tí wọn yó sì máa gbá ojú wọn àti ẹ̀yìn wọn |