Quran with Yoruba translation - Surah Al-hujurat ayat 18 - الحُجُرَات - Page - Juz 26
﴿إِنَّ ٱللَّهَ يَعۡلَمُ غَيۡبَ ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِۚ وَٱللَّهُ بَصِيرُۢ بِمَا تَعۡمَلُونَ ﴾
[الحُجُرَات: 18]
﴿إن الله يعلم غيب السموات والأرض والله بصير بما تعملون﴾ [الحُجُرَات: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú Allāhu mọ ìkọ̀kọ̀ àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀. Àti pé Allāhu ni Olùríran nípa ohun tí ẹ̀ ń ṣe níṣẹ́ |