Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 19 - قٓ - Page - Juz 26
﴿وَجَآءَتۡ سَكۡرَةُ ٱلۡمَوۡتِ بِٱلۡحَقِّۖ ذَٰلِكَ مَا كُنتَ مِنۡهُ تَحِيدُ ﴾
[قٓ: 19]
﴿وجاءت سكرة الموت بالحق ذلك ما كنت منه تحيد﴾ [قٓ: 19]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé ìpọ́kàkà ikú yóò dé láti fi òdodo ọ̀run rinlẹ̀. Ìyẹn ni ohun tí ìwọ ń sá fún |