Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 21 - قٓ - Page - Juz 26
﴿وَجَآءَتۡ كُلُّ نَفۡسٖ مَّعَهَا سَآئِقٞ وَشَهِيدٞ ﴾
[قٓ: 21]
﴿وجاءت كل نفس معها سائق وشهيد﴾ [قٓ: 21]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ̀mí kọ̀ọ̀kan yóò wá pẹ̀lú olùdarí kan àti ẹlẹ́rìí kan (nínú àwọn mọlāika) |