Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 27 - قٓ - Page - Juz 26
﴿۞ قَالَ قَرِينُهُۥ رَبَّنَا مَآ أَطۡغَيۡتُهُۥ وَلَٰكِن كَانَ فِي ضَلَٰلِۭ بَعِيدٖ ﴾
[قٓ: 27]
﴿قال قرينه ربنا ما أطغيته ولكن كان في ضلال بعيد﴾ [قٓ: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Èṣù) alábàárìn rẹ̀ yóò wí pé: "Olúwa wa, èmi kọ́ ni mo ṣì í lọ́nà, ṣùgbọ́n ó ti wà nínú ìṣìnà tó jìnnà (sí òdodo) tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ |