Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 28 - قٓ - Page - Juz 26
﴿قَالَ لَا تَخۡتَصِمُواْ لَدَيَّ وَقَدۡ قَدَّمۡتُ إِلَيۡكُم بِٱلۡوَعِيدِ ﴾
[قٓ: 28]
﴿قال لا تختصموا لدي وقد قدمت إليكم بالوعيد﴾ [قٓ: 28]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Allāhu) yóò sọ pé: "Ẹ má se ṣàríyànjiyàn lọ́dọ̀ Mi. Mo kúkú ti ṣe ìlérí fun yín ṣíwájú |