Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 29 - قٓ - Page - Juz 26
﴿مَا يُبَدَّلُ ٱلۡقَوۡلُ لَدَيَّ وَمَآ أَنَا۠ بِظَلَّٰمٖ لِّلۡعَبِيدِ ﴾
[قٓ: 29]
﴿ما يبدل القول لدي وما أنا بظلام للعبيد﴾ [قٓ: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn kò sì lè yí ọ̀rọ̀ náà padà ní ọ̀dọ̀ Mi. Èmi kò sì níí ṣe àbòsí sí àwọn ẹrú Mi |