Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 31 - قٓ - Page - Juz 26
﴿وَأُزۡلِفَتِ ٱلۡجَنَّةُ لِلۡمُتَّقِينَ غَيۡرَ بَعِيدٍ ﴾
[قٓ: 31]
﴿وأزلفت الجنة للمتقين غير بعيد﴾ [قٓ: 31]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n máa sún Ọgbà Ìdẹ̀ra mọ́ àwọn olùbẹ̀rù (Allāhu). Kò sì níí jìnnà (sí wọn) |