Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 45 - قٓ - Page - Juz 26
﴿نَّحۡنُ أَعۡلَمُ بِمَا يَقُولُونَۖ وَمَآ أَنتَ عَلَيۡهِم بِجَبَّارٖۖ فَذَكِّرۡ بِٱلۡقُرۡءَانِ مَن يَخَافُ وَعِيدِ ﴾
[قٓ: 45]
﴿نحن أعلم بما يقولون وما أنت عليهم بجبار فذكر بالقرآن من يخاف﴾ [قٓ: 45]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwa nímọ̀ jùlọ nípa ohun tí wọ́n ń wí. Ìwọ kò sì níí jẹ wọ́n nípá (láti gbàgbọ́). Nítorí náà, fi al-Ƙur’ān ṣe ìrántí fún ẹni tí ń páyà ìlérí Mi |