Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 44 - قٓ - Page - Juz 26
﴿يَوۡمَ تَشَقَّقُ ٱلۡأَرۡضُ عَنۡهُمۡ سِرَاعٗاۚ ذَٰلِكَ حَشۡرٌ عَلَيۡنَا يَسِيرٞ ﴾
[قٓ: 44]
﴿يوم تشقق الأرض عنهم سراعا ذلك حشر علينا يسير﴾ [قٓ: 44]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Rántí) ọjọ́ tí ilẹ̀ yóò fàya pẹ́rẹpẹ̀rẹ mọ́ wọn lára, (tí wọn yóò máa) yára (jáde láti inú ilẹ̀). Ìyẹn ni àkójọ t’ó rọrùn fún Wa |