Quran with Yoruba translation - Surah Qaf ayat 8 - قٓ - Page - Juz 26
﴿تَبۡصِرَةٗ وَذِكۡرَىٰ لِكُلِّ عَبۡدٖ مُّنِيبٖ ﴾
[قٓ: 8]
﴿تبصرة وذكرى لكل عبد منيب﴾ [قٓ: 8]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ó jẹ́) àríwòye àti ìrántí fún gbogbo ẹrúsìn tó ń ṣẹ́rí padà (síbi òdodo) |