Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 47 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿وَٱلسَّمَآءَ بَنَيۡنَٰهَا بِأَيۡيْدٖ وَإِنَّا لَمُوسِعُونَ ﴾
[الذَّاريَات: 47]
﴿والسماء بنيناها بأيد وإنا لموسعون﴾ [الذَّاريَات: 47]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé sánmọ̀, A mọ ọ́n (sí òkè yín) pẹ̀lú agbára. Dájúdájú Àwa sì ni olùgbòòrò |