Quran with Yoruba translation - Surah Adh-Dhariyat ayat 48 - الذَّاريَات - Page - Juz 27
﴿وَٱلۡأَرۡضَ فَرَشۡنَٰهَا فَنِعۡمَ ٱلۡمَٰهِدُونَ ﴾
[الذَّاريَات: 48]
﴿والأرض فرشناها فنعم الماهدون﴾ [الذَّاريَات: 48]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti ilẹ̀, A ṣe é ní ìtẹ́. Àwọn olùtẹ́lẹ̀-sílẹ̀ sì dára |