Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 27 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿فَمَنَّ ٱللَّهُ عَلَيۡنَا وَوَقَىٰنَا عَذَابَ ٱلسَّمُومِ ﴾
[الطُّور: 27]
﴿فمن الله علينا ووقانا عذاب السموم﴾ [الطُّور: 27]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣùgbọ́n Allāhu ṣàánú wa. Ó sì là wá níbi ìyà Iná |