Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 31 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿قُلۡ تَرَبَّصُواْ فَإِنِّي مَعَكُم مِّنَ ٱلۡمُتَرَبِّصِينَ ﴾
[الطُّور: 31]
﴿قل تربصوا فإني معكم من المتربصين﴾ [الطُّور: 31]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: "Ẹ máa retí. Dájúdájú èmi náà wà pẹ̀lú yín nínú àwọn olùretí |