Quran with Yoruba translation - Surah AT-Tur ayat 30 - الطُّور - Page - Juz 27
﴿أَمۡ يَقُولُونَ شَاعِرٞ نَّتَرَبَّصُ بِهِۦ رَيۡبَ ٱلۡمَنُونِ ﴾
[الطُّور: 30]
﴿أم يقولون شاعر نتربص به ريب المنون﴾ [الطُّور: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tàbí wọ́n ń wí pé: "Eléwì kan tí à ń retí ikú rẹ̀ ni |