×

Ko si imo kan fun won nipa re. Won ko si tele 53:28 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah An-Najm ⮕ (53:28) ayat 28 in Yoruba

53:28 Surah An-Najm ayat 28 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah An-Najm ayat 28 - النَّجم - Page - Juz 27

﴿وَمَا لَهُم بِهِۦ مِنۡ عِلۡمٍۖ إِن يَتَّبِعُونَ إِلَّا ٱلظَّنَّۖ وَإِنَّ ٱلظَّنَّ لَا يُغۡنِي مِنَ ٱلۡحَقِّ شَيۡـٔٗا ﴾
[النَّجم: 28]

Ko si imo kan fun won nipa re. Won ko si tele kini kan bi ko se aroso. Dajudaju aroso ko si nii roro kini kan lara ododo

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وما لهم به من علم إن يتبعون إلا الظن وإن الظن لا, باللغة اليوربا

﴿وما لهم به من علم إن يتبعون إلا الظن وإن الظن لا﴾ [النَّجم: 28]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Kò sí ìmọ̀ kan fún wọn nípa rẹ̀. Wọn kò sì tẹ̀lé kiní kan bí kò ṣe àròsọ. Dájúdájú àròsọ kò sì níí rọrọ̀ kiní kan lára òdodo
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek