Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qamar ayat 12 - القَمَر - Page - Juz 27
﴿وَفَجَّرۡنَا ٱلۡأَرۡضَ عُيُونٗا فَٱلۡتَقَى ٱلۡمَآءُ عَلَىٰٓ أَمۡرٖ قَدۡ قُدِرَ ﴾
[القَمَر: 12]
﴿وفجرنا الأرض عيونا فالتقى الماء على أمر قد قدر﴾ [القَمَر: 12]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A tún mú àwọn odò ṣẹyọ lórí ilẹ̀. Omi (sánmọ̀) pàdé (omi ilẹ̀) pẹ̀lú àṣẹ tí A ti kọ (lé wọn lórí) |